Afe Aye - Psalmos Full Complete Lyrics
Chorus Ninu afe aye Baba j’nle tele o Ninu afe ile aye Je nle tele o Verse 1 What shall it profit a man to gain the world and lose his soul. Ile aye yii dun ladunju Sugbon igbeyin re koro bi iwo Ile aye baje o balumo O olu orun dakun maje sise Maje fi adun ileaye o baba mi Ki n fi ba ti orunje Ko si bi aye tile dun to Orun a dun ju ile aye lo Repeat Chorus Verse 2 The heart is deceitful above all things and desperately wicked who I mean who can know it Orun o gbe e Iro laye mo n Afojo bori Elesan wo o lorun Idajo o le ro Iku l’ere ese Eda adariwurun Eeje a sora siwa wu Ka mo ba oja je Ka tun ba ale je E ni awo e gbodo woran chorus
Comments
Post a Comment
Thanks For Commenting!